(Chorus) Tíń-tín-tín, ó ń dún, Agogo ilé-ìwé wa. Tíń-tín-tín, ó ń dún, Ó pè wá sí kílásì.
(Verse 1) Mo ji l’owuro, mo wẹ, mo wọ uniform, Mummy say “ọmọ mi, gbiyanju, make you perform.” Bẹ́lì na sound, tíń-tín-tín, I carry book, I carry dream. I no dey play, mo fẹ̀ kọ ẹ̀kọ, I dey follow teacher like I dey chase gold. Na A B C we dey decode, Ojú mi l’ori board, I dey enter mode.
(Chorus) Tíń-tín-tín, ó ń dún, Agogo ilé-ìwé wa. Tíń-tín-tín, ó ń dún, Ó pè wá sí kílásì.
(Verse 2) Tíń-tín-tín, kò sí dulling, Kílásì dey hot, gbogbo brain dey boiling. Teacher wa ni chalk, a wa ni jotting, Ojú kọ ni mo fi n gbọ́ lesson. Aja pako, but àgbọ́n l’ókàn, Future bright, mo mọ pé mo gbọ́ nkan. Agogo n pè wa, kò sí delay, Ilé-ìwé ni mo ti máa gba way.
(Verse 3) Ó ń tọ́ka sí àkókò, Fún wá láti kọ́wé. Ó ń tọ́ka sí àkókò, Fún wá láti kẹ́kọ̀ọ́. (Chorus) Tíń-tín-tín, ó ń dún, Agogo ilé-ìwé wa. Tíń-tín-tín, ó ń dún, Ó pè wá sí kílásì.
(Chorus) Tíń-tín-tín, ó ń dún, Agogo ilé-ìwé wa. Tíń-tín-tín, ó ń dún, Ó pè wá sí kílásì.
In order to confirm the bank transfer, you will need to upload a receipt or take a screenshot of your transfer within 1 day from your payment date. If a bank transfer is made but no receipt is uploaded within this period, your order will be cancelled. We will verify and confirm your receipt within 3 working days from the date you upload it.